Peter obi le bori gbogbo Awon alatako re ni ile Ariwa orilede Nigeria.”Jerry Gana”

Okan pataki Lara Awon oludasile Egbe oselu PDP, Ojogbon Jerry Gana ti so pe Gomina ni igbakan ri ti Anambra ti o tun je Asoju Egbe labour ni inu ibo are ti odun 2023 to koja le bori gbogbo Awon alatako re ni ile Ariwa orilede Nigeria.

Ni Igba TI i so oro ni inu iforowero ni ojoru, Gana so pe,oun je oni no ijinle iwadi ti oun si ma n se iwadi nipa Erongba Awon eniyan.Ni Awon ile Ariwa. Bi Peter ba wa si inu Egbe PDP yio bori Awon akegbe re ni inu ibo ti ile Ariwa, Tori Awon ara Ariwa je oni inu mimo at Oloto.

Peter obi eni to kuro ni inu Egbe PDP ni osu karun odun 2022 lo di inu Egbe oselu Labour Party, ti o si jade gege bi oludije gege bi are ni odun 2023.

O te si waju pe” opo eyan lo ti gbagbe oe PDP je Egbe oselu ti owa lati ibere Pepe ti won da sile ni odun 1998, ti won si bere eto idibo ni odun 1999, ti o si je Egbe PDP ni Egbe akoko ti o koko wole eto idibo ni orilede Nigeria.

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here