
ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Jigawa ti mú àwọn èèyàn méje tí wọ́n fura pé wọ́n jẹ́ olùtajà òògùn olóró, pẹ̀lú àwọn mìíràn, lẹ́yìn àwọn iwode tó waye káàkiri ìpínlẹ̀ náà.
Atejade yìí wà nínú ọ̀rọ̀ tí Alákóso Ìbánisọ̀rọ̀ fún Ọ́fíìsì ọlọ́pàá náà, SP Shi’isu Adam, fi síta ní ọjọ́ Ajé ní Dutse, olúìlú ìpínlẹ̀ náà.
Gẹ́gẹ́ bí Atejade náà ṣe sọ, a ṣe ise iwadi to yori si mimu awon Eyan yii láàárín ọjọ́ ketadinlogbon osu keje (July 27) si ọjọ́ kini oṣù kejo (August8) ọdún 2025.
Ise wọ̀nyí dá lórí àlàyé tí wọ́n gba, tí ó sì yọrí sí gbigba àwọn òògùn olóró tó pọ̀, àwọn ohun-ini tó je jiji, àti àwọn ọkọ ti won tun ji na pelu.
Kòmíṣọ́nà ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ náà, CP Dahiru Muhammad, yìn àwọn ọlọ́pàá fún ise ti won se lai fi fale àti tó munadoko.
Ó ní: “A ó tẹ̀síwájú láti jẹ́ ki ayé ààbò àti àlàáfíà wa fún gbogbo ènìyàn.”
Atejade náà tún ṣàfihàn pé àwọn aṣeyọrí ọlọ́pàá ní àkókò yìí ní àfikún pe won mu àwọn tí wọ́n fura pé wọ́n jẹ́ Awon , ajinigbé, àti àwọn tí wọ́n máa máa jí oun oni Awon eyan papa julo okada.
“Àwọn afurasi náà wà ní odo Awon olopa bayìí, wọ́n sì ń ràn ọlọ́pàá lọ́wọ́ pẹ̀lú ìwádìí tó ń lọ.
SP Adam sọ pé: “A ó fi afurasi náà lé Ẹgbẹ́ Ilẹ̀ Nàìjíríà tó ń ṣàkóso àwọn òògùn olóró (NDLEA) lọ́wọ́ fún iwadi.”

