Ijamba waye ni ipinle Ogun,Ero okada padanu emi re

Ero Ori okada kan iyun arabirin kan ni o ti ku si inu isele ijamba, leyin ti awako kan Ko Lu won ni opopona Igan ni agbegbe Ago iwoye ni Ipinle Ogun.

Sugbon ti olokoda oun si fi ara pa yanna yann, ni inu isele oun to waye ni ojoru ose ti awa yii

Alukoro Ajo ton ri si Eto irina ati ofin irinna ni ipinle Ogun, Babatunde Akinbiyi lo fi iroyin oun lede pelu Akoroyin wa ni Ojoru ana.

Gege bi Akinbiyi se so”oni isele lo sele larin oko Toyota Camry kan pelu numba JJJ 168VY Ati Okada Bajaj kan pelu numba KNN873 ZY

“One female died and one male was injured.

O fi kun pe” Eni ti iroyin oun soju re je ki o di mimo pe Awako Camry oun ni o wa iwa ku wa ti o si Ko lu olokada oun ton bo lona. Ti o si ni obirin kan si ku lóju ese ti olokada na si fi arapa.

Ti eleyi si fa sun Kere fa Kere oko sungbon pelu iranlowo Àwon eso oju popo to je aladani won rii yanju, ti won si gbe oko Ati okada ti o ni ijamba oun kuro lóju ona.

Iroyin pada je ki o di mi mo pe ijamba mi tun waye ni ojo isegun Tuesday ti Àwon meji si won padanu emi won ninu ijamba oun ti gbo gbo oju opopona Oju Ona Eko si Ibadàn si di pa latari isele oun

Isele ti gba emi eyan meji oun lo waye oju ona oun ni Dede Ago mejo aro.

Oni Kontena (container) lo jabo ni tosi adari Otedola to si pa Àwon eyan oun.

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here