“Gossima Tí Wọ́n Mú Lórí Ayélujára, Ọlọ́pàá Sọ Pé Kò ní Ímọ Ọṣèlú ninu”

Àwọn Ọlọ́pàá Nípínlẹ̀ Jigawa Ṣàlàyé Ìdìí Tó Fà gbigbe ti won gbe Abubakar Gossima, Wọ́n Ní Kò Ní Nkan kan se Ọ̀ràn Ọṣèlú Kankan.

Ká rántí pé Abubakar Gossima, ọmọ ẹgbẹ́ All Progressives Congress (APC) nípínlẹ̀ Jigawa, ni wọ́n sọ pé àwọn ọlọ́pàá mu lọ́jọ́bọ́ tí kọjá , ní ìlú Bulangu ni ìjọba ìbílẹ̀ Kafin Hausa.

Ìròyìn yìí sọ pé esun ti won fi kan Gossima  ni pe omo ẹgbẹ́ APC mìíràn, Aliyu Suleiman, ni o fi esun kàn án ni pé Gossima ṣòro nípa bi ose soro lo bi ose fe  ṣojú ilú ní Ilé aṣòfin àpapọ̀, nínú oju opo ero ayelujara tó fi sí àwọ̀n àgbáyé lórí ayélujára.

Síbẹ̀, ti iwoye àwọn ènìyàn ni pé ọ̀ràn ọṣèlú ni o fa ti won fi mu.

Ṣùgbọ́n nigba ton so ni inu oro re, agbẹnusọ ọlọ́pàá nípínlẹ̀ Jigawa, SP Shi’isu Adam, sọ ní Dutse ní ọjọ́ Sátidé pé:

“Awon Olopa nípínlẹ̀ Jigawa ti wà lórí àwọn ìròyìn tó ń tan káàkiri lórí ero ayelujara àgbáyé pé a mú Abubakar Gossima fún oro ọṣèlú, Ìyẹn jẹ́ àlàyé àṣìṣe, ti a ní láti ṣàtúnṣe rẹ̀.”

Mimu Gossima jẹ́ iṣẹ́ àwọn ọlọ́pàá ti Special Investigation Unit Force Headquarters ní Abuja.

Àwọn ọlọ́pàá ní wọ́n ṣo pe ni pase  òfin àti àṣẹ ilana a tele gẹ́gẹ́ bí ìjọba ṣe yàn wọ́n ni awon fi gbe ise won jade.

SP Adam be gbogbo àwọn aráàlú àti àti awon eyan Lori ero ayelujara lati máa ṣàyẹ̀wò ìtàn dájú kó tó di pé wọ́n tàn án káàkiri kí wọ́n má bà gbogbo ènìyàn jẹ́ pẹ̀lú àlàyé tí kò pé.

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here