Ajo LAWMA ipinle Eko mu awon eyan meji lori dida ile si ibi ti ko to.

Àjọ Tó N Rí Sí Ọ̀rọ̀ awon ile didanu ni Ayinke ni ilu Eko (LAWMA) ti sọ pé wọn ti mu obìnrin méjì, Margaret Solomon ati Onyia Elizabeth,lọ́jọ́ ẹjọ́ pé wọn ju da ile síta níbi tí kò tọ́, tí wọn sì kọ̀ láti tẹ̀lé òfin tó yẹ.

Wọ́n ní wọ́n mú wọn ní alẹ́ ní Sangotedo lo oju ona Lekki Expressway, láàárín alẹ́ Ọjọ́ Tuesday àti òwúrọ̀ Ọjọ́ Wednesday, nígbà tí ẹgbẹ́ LAWMA tó n ṣàbewo si Àwon agbegbe.

Gẹ́gẹ́ bí Muyiwa Gbadegeshin, Alákóso Agba LAWMA, ṣe fi síta lórí ojú-ìwé X rẹ ní Ọjọ́ Thursday, ó ní lẹ́yìn tí wọ́n mú àwọn obìnrin náà, wọ́n ò lè sọ adirẹ́sì ile wọn gan-an dáadáa, wọ́n sì ti fi wọn lé ọwọ́ agbẹjọ́rò LAWMA fún ẹjọ́.

Ó ní gbogbo ará ìlú ní ẹ̀tọ́ àti ojúṣe lábẹ́ òfin láti ju ile wọn síbi tó yẹ, kí wọn sì mọ̀ ibi tó tọ́ láti fi ile wọn sí, kí wọ́n tẹ̀lé òfin tó jẹ́ ti itoju Ayoka.

Muyiwa tún rọ àwọn ará ìlú pé kí wọ́n forúkọ sílẹ̀ pẹ̀lú àwọn tó n kó idoti gẹ́gẹ́ bí LAWMA ṣe yàn, kí wọ́n ra agbọn amójútó tí LAWMA fọwọ́ sí, kí wọ́n san owó wọn bó ṣe yẹ, kí wọ́n má ju idoti sí ibi tí kò bófin mu, kí wọ́n sì lo ibi tí a ti yàn lati ma ju ile si.

Ó tún sọ pé ẹnikẹ́ni tó bá kọ láti tẹ̀lé òfin yìí lè di ero atimole fun osu mefa abi San owo itanran N250,000.

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here