ADC fesi si oro ti APC fi ranse si Awon olori won (Obi,Atiku,El-rufai,Amaechi)

Ẹgbẹ́ olóṣèlú African Democratic Congress (ADC), fe si pada si oro ti  All Progressives Congress (APC) so oro si Awon olori Egbe na àti pé wọ́n pè ẹgbẹ́ àjọṣepọ̀ náà ní ewu kedere àti oun tó lewu sí orílẹ̀-èdè yìí.

APC sọ pé àwọn olórí ADC, tó fi mọ́ igbakeji ààrẹ teleri, Atiku Abubakar; olùdíje ààrẹ lórílẹ̀-èdè Nigeria ni inu ẹgbẹ́ Labour ní ìbò ọdún 2023, Peter Obi; Gómìnà ìpínlẹ̀ Kaduna tẹ́lẹ̀, Nasir el-Rufai; àti Gómìnà ìpínlẹ̀ Rivers tó ti kúrò nípò, Rotimi Amaechi, won se apejuwe won gege nu àwọn olósèlú, ti ko ni  Afojusun atí ti kò ní ìtòsọ́nà

Wọ́n kìlọ̀ fún àwọn ará Nàìjíríà pé kí wọ́n ṣọ́ra fún àwọn olóṣèlú tó ń lo ẹ̀yà àti ẹ̀sìn gẹ́gẹ́ bí oun ijagun ati ipolongo won, tí wọ́n sì fẹ́ da asa ìyípo ààrẹ sile, tí ó ń yípo láàárín ariwa àti guusu.

ADC sọ pé àwọn àtúnṣe orí ìsúná tó ń bẹ lásìkò Ààrẹ Bola Tinubu jẹ́ eleyi ti Ko Dara to atipe o buru jai. Nígbà tó yá, Coalition of United Political Parties (CUPP) sọ pé àtakò APC sí Peter Obi jẹ́ àgbékalẹ̀ láti yí ìfọkànbalẹ̀ àwọn aráyé padà kúrò lórí àwọn iṣoro tòótọ́.

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here