NEWS
movies
ENTERTAINMENT
FEATURED
IROYIN
Imamu Agba ti won ji gbe ni ipinle Edo gba Itusile
Ile-ise ọlọ́pàá ipinlẹ Edo ti kede ìtúsilẹ imamu Agba ilẹ̀ Uromi ti ipinle na, Sheikh Moritada Obhakhoboh, lọwọ́ àwọn tí wọ́n jí í gbe.
Agbẹnusọ...
Eto isinku Are Buhari ni oni yii
Gomina ipinlẹ Katsina, Malam Dikko Radda, ti ṣalaye bi eto isinku Aarẹ ana ti Naijiria, Muhammadu Buhari, yoo sewaye.
Buhari ku ni ilu London lẹyin...
Àwọn ajinigbe gbe Kontrator ni Ìpínlẹ̀ Delta, Béèrè Owó Ìdálẹ́kọ̀ọ́ Milionu lo...
Àwọn Afurasi Ajinigbé ni wọn ti gbé ọmọ osise ijoba kan iyun kontrator (Goverment contractor), Ogbeni Lucky Ugbo, ní Ogwashi-Uku, ìjọba ìbílẹ̀ Aniocha, ni...
Ìlú Abia Kò Ní Dàrú – Ọlọ́pàá gba owo to to milionu meji owo...
Ile-ise ọlọ́pàá ni ipinle Abia, ni ọjọ́ Sátidé, gbà àwọn ènìyàn mẹ́ta tí wọ́n ji kuro lowo tí wọ́n tún gba mílíọ̀nù meji ti...
Ìjàmbá Ọkọ to Burú Lórí Afárá Udu ti Eni Mẹ́fà si ku
Àwọn òkú mẹ́fà ni wọ́n kó kúrò níbi ìjàmbá ọkọ tó ṣẹlẹ̀ ní ọ̀sán ọjọ́ Ajé lórí afárá Udu ní Ìpínlẹ̀ Delta, lẹ́yìn tí...